Are you an artist? Make the most of your lyrics with Musixmatch Pro!
Add translation
Share
Verified by Curator
14 contributions
almost 4 years ago
Translations

Lyrics of Mimo by Sola Allyson Obaniyi

Mimo Mimo Mimo s′Olodumare, oju elese ko le ri ogo Re
Baba Alagbara, Baba imole
Gbogbo ope, gbogbo ogo ni f'oruko Re
Hmmn hmmn, maa joba lo Oluwa, maa joba lo Kabiyesi Olola maa joba lo
Maa joba lo Oluwa, ko s′elomiran leyin Re, Baba Imole, maa joba lo
Oba t'a ko le ro loye, alagbara t'a ko le segun ni Ijoba Re dun mo wa, o dun mo wa o
Maa joba lo
Maa joba lo Oluwa
Oba t′a ko le ro loye, Alagbara t′a ko le segun ni
Ijoba Re dun mo wa yeye oooo
Ma joba lo Oluwa
(Maa aa joba lo)
Ma joba lo Oluwa
Oba t'a ko le ro loye, Alagbara t′a ko le segun ni
Ijoba Re dun mo wa yeye oooo
Ma joba lo Oluwa
Ola le wo laso, ogo laso ileke, iyin le gun lesin, Awamaridi Olodumare
Iyin le gun lesin, Awamaridi Olodumare
A o ri Yin, sugbon a mo pe E j'olododo
A o r′oju Yin o, sugbon a m'oju Yin fun aanu to po
A o m′ola t'owo Yin ko, sugbon a r'owo Yin lara ohun gbogbo eeh
Kabiyesi wa gb′ola Re
Iwo nikan ma ni, Iwo lo da ohun gbogbo
Gbogbo ola, gbogbo ogo, gbogbo iyin, gbogbo agbara Iwo lo ni
Maa s′ola Re lo ninu ola
Maa s'ola Re lo
Kabiyesi wa gb′ola Re
Olorun ti gbe ni ga, Olorun ti fi ni m'ona, Olorun ti to′ni s'ona, mo se′ba Re, Oba ase're maa se'bi, Oba tii f′ayo pon ni le,
Oloju aanu ni O o, Baba to f′aanu han si mi, maa s'ola Re lo
Kabiyesi wa gb′ola Re
Oba oke, Oba gegele, Oba omi, Oba okun, Oba eranko inu igbo (Kabiyesi wa gb'ola Re) Oba eye to n fo loju orun maa s′ola Re lo, maa s'ola Re lo
Awon orun n soro ogo Re (Kabiyesi wa gb′ola Re)
Ofurufu n f'ise Re han (Kabiyesi wa gb'ola Re)
Ojo de ojo n fohun, igba de igba n fi imo ogo Re han
Kabiyesi maa s′ola Re lo
Hmmmn hmmmn hmmmmn
Lese ite Re la wo′le
A m'ope wa
A mu′yin wa
A f'oribale fun o Baba
Iwo nikan logo to si
Iwo nikan lola to si oo
Baba ta lo dabi Re, ta lo dabi Re oh oh oh oh
Ta la ba fi o we, ta lo le ba O d′ogba?
Ta la ba fi o we, ta lo le ba O d'ogba o?
Olorun to j′Olorun, ta la ba fi O we?
Ta la ba fi o we, ta lo le ba O d'ogba?
Olorun to j'Olorun, ta la ba fi O we?
Ta la ba fi o we, ta lo le ba O d′ogba?
Olorun to j′Olorun, ta la ba fi O we?
Ta la ba fi o we, ta lo le ba O d'ogba?
Olorun to j′Olorun, ta la ba fi O we?
You are the Reason why we are singing
Jehovah (You are the Most High God)
For You are the Reason why we are living Jehovah (You are the Most High God)
Jehovah (You are the Most High)
Jehovah (You are the Most High God)
Jehovah Elohim, Jehovah Rapha (You are the Most High)
Jehovah (You are the Most High God)
Enu wa yo ma ko'rin iyin Re nigba gbogbo (You are the Most High)
Iyin Re yi aye ka (You are the Most High God)
Oba Alaanu, Oba Oloore ofe, Jehovah Jehovah (You are the Most High)
Oluwa, Iwo ni o ye lati gba gbogbo ogo at′ola o (You are the Most High God)
Ti o ba si Iwo, nibo lemi gangan o ba wa o? (You are the Most High)
Oba to f'agbara gba′ni lowo alagbara gbagba ti f'owo agbara je ni niya (You are the Most High God)
Eeeeh Jehovah Jehovah mo yin oruko Re o (You are the Most High)
Baba Alaanu mi, Baba Oloore mi (You are the Most High God)
Iyin Re yi aye ka, iyin Re gba gbogbo okan mi o (You are the Most High)
Arugbo Ojo, Adagbamatepa, Baba o, Baba o (You are the Most High God)
Eh eh eh eh Jehovah ah ah ah (You are the Most High)
Jehovah ah ah (You are the Most High God)
You are the Reason why we are living, why we are singing (You are the Most High)
Nitori Re la se wa, la se n rin. la se n yan fanda o
(You are the Most High God)
Ife Re nikan lo gbe wa ro, Jehovah wa gb'ope o, (You are the Most High) wa gba′yin, wa gb′ogo, wa gb'ola Re o (You are the Most High God)
Jehovah ah ah (You are the Most High)
Jehovah ah ah (You are the Most High God)
Jehovah Rapha, Jehovah Shammah, Jehovah Elohim (You are the Most High)
The Mighty Man in battle we praise You (You are the Most High God)
Olorun mi Iwo ni maa sin titi aye mi, Amin o
(Eje mi niyen Baba oo)
Lojo mo rije eeeh, Oluwa la t′odo Re wa
Lojo mo rimu oooh, Oluwa la t'odo Re bo
Bi mo ti n r′ayo se Iwo lo n fun mi layo se (Oluwa la t'odo Re wa)
Bi mo ti n r′ebun lo, Iwo lo n fun mi lebun lo Baba mi (Oluwa la t'odo Re bo)
Olorun mi Iwo ni maa sin titi aye mi, Amin o
Ore ofe Re to, o to fun mi o
Emi le s'ohun gbogbo
Emi yo sin O titi aye mi Baba mi o
Eni to ni′gba mi Iwo ni maa sin titi aye mi, Amin o
Olu funni lebun to fun mi lebun ose o Baba
Lojo mo rije eeeh, Oluwa la t′odo Re wa
Lojo mo rimu Baba mi o, Oluwa la t'odo Re bo
Bi mo ti n lo, bi mo ti n bo, ti mo n yan fanda fanda (Oluwa la t′odo Re wa)
Bi mo ti n r'ayo se, ti mo n r′ogo lo, Iwo lo n fun mi logo lo (Oluwa la t'odo Re bo)
Baba Baba Baba o
Olorun mi Iwo ni maa sin titi aye mi, Amin o (Eni to ni gba mi, Iwo ni maa sin, eje mi re o eje mi)
Writer(s): Sola Allyson

Contribute

To-do

Structure Tag
Identify the song's sections

Completed

Lyrics
Verified by Curator
Performers Tag
Identify who's singing what

Credits

This song has no credits yet

Contributions

Last edit almost 4 years ago
Show 14 contributors
Are you an artist? Distribute your lyrics!
Take full control of your lyrics. Curate, sync, and distribute your lyrics on Spotify, Apple Music, and more.
Explore Musixmatch Pro