Kabiyesi o Oba to joko lori obiri aye Ogo fooko Re
Oba Ibere, Oba Aarin, Oba to meyin to le sohun gbogbo
Kabiyesi o, awon orun n soro ogo Re, ofurufu n fise Re han
Ise Re po gaan ni ko lafiwe o, a wole a fiyin foruko mimo Re
Kabiyesi o, Baba mi, Olorun mi, Eni to lebun gbogbo
Oba Ibere, Oba Aarin, Oba to meyin to le sohun gbogbo
Oba Ibere, Oba Aarin, Oba to meyin to le sohun gbogbo
Eyin ni Baba to ju baba lo
Baba to lemi mi ogo fooko Re
Iwo ni Baba to ju baba lo
Eyin ni Baba to ju baba lo
Eyin ni Baba to ju baba lo
Eyin ni Baba to ju baba lo
Eyin ni Baba to ju baba lo
A se ite fun O ninu okan wa Iwo ni
Iwo ni Baba to ju baba lo
Inu orin iyin awon eni mimo niwo n gbe Baba
Iwo ni Baba to ju baba lo
Oba to joko lori ite, awon angeli n foribale fun O
Iwo ni Baba to ju Baba lo (Eyin ni)
Eyin ni Baba to ju baba lo
Eyin ni Baba to ju baba lo
Eyin ni Baba to ju baba lo
Eyin ni Baba to ju baba lo
Oba to tan ′mole sona wa, Oun ni
Aye si n be, elese wole wa
Baba wa po ni agbara, O po ni aanu o
Eh eh eh ah e lo simi agbaja
Oun lo tun le aye awa se ge ge
Eh eh eh ah e lo simi agbaja
Oun lo tun le aye awa se ge ge
E wa wo Olurapada Alaanu to n tu ni sile
E wa wo Alara ire Oba to n tun ni se
Eni to wa leyin ogba ko wole wa
Aye si n be ninu ogba Alaanu o
B′omode sun, a fi isori E so
Baba wa sun, a fi isori E so
Ire la mo t'O n gba wa lowo ewu
Hallelujah Ogo ni fun Baba
Ki la fi san j′awon t'iku ti pa
Ire lo s′aabo, alaafia wa
Ire la mo t'O n gba wa lowo ewu
Hallelujah Ogo ni fun Baba
Hallelujah Ogo ni fun Baba
Alaaye ni yoo yin O bo ti ye
Hallelujah Ogo ni fun Baba
Hallelujah Ogo ni fun Baba
A fijo filu yin Olorun wa
Alaaye ni yoo yin O bo ti ye
Oluwa Oba to mo Dafidi fi isori E so wa
Oluwa Oba to mo Dafidi fi isori E so wa
Oluwa Oba to ni ike ige fi isori E so wa eeeh
Oluwa Oba to ni ike ige fi isori E so wa
Eni to joko lori ite ogo fooko Re
Ope ye oruko Re Iwo nikan ni
Tani n ba sin bi o se 'Wo
Oba to f'aanu tan ′mole sona mi
Orin yi naa ni emi o maa ko
Orin irapada imole t'O tan fun mi
Aanu n mo ri gba, ookun pada di′mole lona mi