Eda to ba mo ise okun kun lyrics lyrics

Get lyrics of Eda to ba mo ise okun kun lyrics song you love. List contains Eda to ba mo ise okun kun lyrics song lyrics of older one songs and hot new releases. Get known every word of your favorite song or start your own karaoke party tonight :-).


Tope Alabi - Afoju Lyrics
Lyrics for Afoju by Tope Alabi. To ba n rin l'okunkun ko le mo, afoju ni To ba n jeun eleera ko le mo, afoju ni To ba r'om...
Tope Alabi - Orun Oun Aye Lyrics
Orun oun aye kun fun ogo Re Orun oun aye kun fun ogo Re Egbegberun awon irawo kede ogo Re Kinni o waa se mi, ti n o ni le maa juba Re o e Didara orun oun so togo Re o Olorun Ewa Re to yi aye ka n so togo Re bo ti po to Gbogbo eda eranko at'ewebe n yin O o Ise owo Re gbogbo lo n keyin le, won yin O o Baba Orun oun aye kun fun ogo Re Orun oun aye kun fun ogo Re Egbegberun awon irawo kede ogo Re ...
Sola Allyson Obaniyi - Ope Lyrics
Lyrics for Ope by Sola Allyson Obaniyi. ... mo se ba Re Oba to ju gbogbo oba lo Kabiyesi ooo Kabiyesi o mo se 'ba Re Oba to ju gbogbo oba lo Afuye gege ti o see gbe Jigbinni jigbinni bi ate ileke Kabiyesi o mo se 'ba Re Oba to ju gbogbo oba lo Afuye gege ma ma see gbe Jigbinni jigbinni bi ate ileke Kabiyesi o mo se 'ba Re Oba to ju gbogbo oba ...
Tope Alabi - Odara Ni Ife Lyrics
The Lyrics for Odara Ni Ife by Tope Alabi have been translated into 1 languages E fi'ba fun Un, e yin I o Awon angeli, won n yi ite Re ka Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye
Tope Alabi - Orun Oun Aye translation in English
English translation of lyrics for Orun Oun Aye by Tope Alabi. Orun oun aye kun fun ogo Re Orun oun aye kun fun ogo Re Egbegberun awon irawo kede ogo Re ...
Tope Alabi - Oro Kan Soso Lyrics
The Lyrics for Oro Kan Soso by Tope Alabi have been translated into 1 languages Oro kan soso Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso Ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o
Tope Alabi - Ibinu Sinmi Laya Were Lyrics
Lyrics for Ibinu Sinmi Laya Were by Tope Alabi ... E wose Satani eeni eko Ibinu simi laye were Beeni Bibeli mi wi fun mi Oko to nbimu lu 'yawo e se lese e Iyawo to nbinu ba nkan ini je Oninu fufu to nja ni hoho ladugbo Won ki i pe so onibinu loruko Bi won o pe ni were, won a pee ni Esu Beeni ire nsa fun oninu fufu Eto Satani f' aye awon eda kan ...
Found 7 lyrics.

Recent lyrics

clumcy